Friday, 28 April 2017

Apology to Ooni of Ife (In Yoruba Language) - HON MOSHOOD SALVADOR


                               Chairman of Lagos State PDP - Hon Moshood Adegoke Salvador

 

Notice : The message below is deliberately written in Yoruba Language, according to the tradition .

Ni oruko gbogbo omo Eko ni tile ti oko. Emi Moshood adegoke Salvador,  omo popo aguda ni eko ile.

A fi towotowo be kabiyesi, Ooni ile ife. Ki ade ki o pe Lori, ki bata ki o pe lese, ki irukere ki o di abere, ki esin oba ki o je oko.

Gbogbo omo Eko toro aforiji lowo kabiyesi.  Ki kabiyesi fi owo wonu o.
Isu eni  ni ntowo  eni bo epo. Oba wa lo nfi eti wa gbo itan kitan.
Ti olorun ba fe ba oba wi.  A gba iwa ni owo re.
Ooni risa, Ojaja 11, Oba Ogunwusi,  Ooni ile ife. Ki fi ori ji wa oo.

Hon Salvador Moshood
State chairman of lagos PDP

6 comments:

 1. Kare Omo Yoruba at at a, Kabiyesi o ko he binu no nitoripe Agba to ko binu lomo re maa nposi. Ti omode ba binu koyan ale, Agba a fi it an bale. Oba yin lobeere it an to aeon Yoruba de fun Ni nkan to nfe. Omo Yoruba at at a kii huwa bee yen.

  ReplyDelete
 2. Ifeoluwa David 0803623140530 April 2017 at 04:02

  Oonirisa Olori alade gbogbo,baba jebure,awo olugbebe,I really appreciate d roles Yoruba has played in this matter, cus d way we handle/honor our traditional rulers, that's how people will treat them,D Oba of Lagos will never attempt such again even to Baale not talking of d Obas cus he has learnt his lesson.
  Long live Oba Ogunwusi Enitan.
  From QS Effective

  ReplyDelete
 3. The issue should not be publicised, let's have a genuine apology but not from opposition political party to score cheap puplicity. What OBA of Lagos did was bad.Its a matter of concern and condemnable by all Yorubas but not be used as political weaponry.

  ReplyDelete
 4. I thank God Almighty and I thanks all the Yoruba's for calming our King The ooni of ife.Gbogno yin e pe fun wa o

  ReplyDelete
 5. Kaare omo Yoruba rere, Kabiyesi ti gbo laafin, eni iyi Ni awon Ara Eko, amo oye Olorun ibi ti eti ri Oba amunibuni eran ibiye. Ose omoluabi Salvador. Kaare eku laakaye

  ReplyDelete
 6. Bo ya oselu ko je oselu....ibi ti a ba pe lori a ki fi tele,ki lode ti awon egbe ti won wa se ijoba lowo o soro.a ni ki apanu po ba ole (thief) eni ibi ti o ni kan fi nkan si o da.....eleko of eko land awa mo wipe oba oselu loje a da awon oba gidi mo. Arole oduduwa oonirinsa ojaja ll enitan ogunwusi kabiesi ooooo

  ReplyDelete